Christmas celebrations: Báyìí ni Odunlade Adekọla, Mide Martins, Mercy Aigbe àtàwọn òṣèré fíìmù Yorùbá míràn kí àwọn olólùfẹ́ wọn kú ọdún

Odunlade adekola ninu aṣọ baba keresi
Published

Wo àwòrán bí ọdún Keresimesi ṣe ń lọ káàkiri àgbàyé

Bi gbogbo agbaye ṣe n ṣajọyọ ọdun Keresimesi lọdun, ọpọ ijọ lo dahoro nitori ajakalẹ arun Covid-19 to n mi agbaye titi.

Amọ ṣa, ọpọ eeyan lo ṣe ọdun naa ni iwọnba bi agbara wọn ṣe mọ ati bi asye ṣe gba wọn si.

Wo diẹw lara aworan bi ọdun keresimesi ọdun 2020 ṣe lọ kaakiri agbaye.

Mercey Aigbe
Mide Martins
Àkọlé àwòrán, Mide Martins naa ki awọn ololufẹ̀ rẹ "Ẹ ku ọdun Keresimesi" lo fi bọnu.
Sydney, Australia
Àkọlé àwòrán, Ni Australia, awọn eeyan wọ aṣọ to n ṣapẹrẹ ọdun naa leti okun.
Pope Francis
Àkọlé àwòrán, Pope Francis dari adura ninu ṣọọṣi St Perter's Basilica ni Vatican.
Pope Francis
Àkọlé àwòrán, Poopu ni asiko yii ki n ṣe asiko lati kaanu ara ẹni, ṣugbọn o jẹ akoko ati ṣe iranwọi fun ẹnikeji.
Christmas Eve Mass in St Peter's Basilica
Àkọlé àwòrán, Ọgunrun eeyan pere lo peju sibi adura maasi.
Children
Àkọlé àwòrán, Awọn ọmọ wẹwẹ tan abẹla lẹnu ọna ijọ Sacred Heart Cathedral, ni Delhi, India
Women
Àkọlé àwòrán, Awọn obinrin wọnyii n gbadura ni kẹlẹkẹlẹ pẹlu ibomu wọn ninu ijọ St Andrew's Church, ni Karachi, Pakistan
Christmas decorations in Woodend
Àkọlé àwòrán, Labule Woodend, iyẹn ni Northamptonshire nilẹ Gẹẹsin, awọn eeyan ṣe ara iule wọn lọṣọ lati sami si ayẹyẹ ọdun naa.
Baghdad, Iraq
Àkọlé àwòrán, Ni Iraq, awọn eeyan gbadura lorukọ Maria Mimọ ni Baghdad
Compostela, Spain
Àkọlé àwòrán, Compostela ree ni Spain
India
Àkọlé àwòrán, Awọn ẹṣọ alaabo wọ aṣọ baba keresimesi ni Rajasthan, India, lati la awọn eeyan lọyẹ nipa ajakalẹ arun Coronavirus.