Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, KO ṢEE MA GBỌ Ọ
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Ọwọ ajọ to n gbogun ti lilo egboogi oloro nilẹ Naijiria, NDLEA tẹ gbajugbaja ori ayelujara kan, KC Luxury

Ki lo wa pa wọn pọ?

NDLEA sọ pe ọwọ tẹ KC Luxury, iyẹn Afolabi Kazeem Michael

Lori ẹsun gbigbe egboogo oloro 184.5kg to le ni miliọnu mejidinlọgbọn owo dọla

Aye o! Oun pẹlu taani?

Ati pe bawo ni aṣiri ṣe tu?

**********************************************************************

Njẹ ipele kẹrin aisan jẹjẹrẹ jẹ idajọ iku bii?

Emi o ma mọ

Awọn akọṣẹmọṣẹ oniṣegun nipa aisan jẹjẹrẹ ṣalaye ohun ti ipele kẹrin tumọ si

Wọn sọ nipa bi aisan jẹjẹrẹ ṣe n tan kaakiri agọ ara

Bẹẹ ni wọn jẹ ko di mimọ pe e

Taraṣaṣa lọ soju opo BBC.COM/YORUBA bi o ba fẹẹ mọ

**********************************************************************

Ẹ gbọ naa, ki lo fa akọtun ija laarin Gomina Dapo Abiọdun ati Ibikunlẹ Amosun

Ṣe kii ṣe lori ọrọ idibo ọdun 2027 ṣa?

Gomina Abiodun so pe iṣakoso oun lo ni ko jẹ ki wọn gbesẹ le ẹsiteeti Buhari to wa niluu Abẹokuta

Ṣe bi Amosun lo bẹrẹ

Bẹẹni, ṣugbọn Amosun naa ti da a pada

Ki lo sọ?