Nibo Laye Koju Si? Àwọn dókítà ti sọ fún mi pé kí n dẹ́kun sígà fífà àti ọtí mímu
Nibo Laye Koju Si? Àwọn dókítà ti sọ fún mi pé kí n dẹ́kun sígà fífà àti ọtí mímu
Published
Ọdun to kọja ni Oloogbe Tope Osoba ṣabẹwo si BBC Yoruba, nibi to ti ṣalaye nipa awọn alakọja rẹ lori aisan jẹjẹrẹ ọmu to kọlu u lojiji.
Bo ṣe gba awọn oṣere ẹgbẹ rẹ lamọran, naa lo tun rọ gbogbo awọn obinrin kaakiri lati maa ṣayẹwo ara wọn loore-koore.
Bakan naa lo tun fidi rẹ mulẹ pe aisan jẹjẹrẹ kii ṣe idajọ iku fun eeyan, nitori pe bi eeyan ba ti ni igbagbọ, to si gba itọju to pe ye, aisan naa yoo poora kuro lara.






