Níbo Layé Kọjú Sí: Ọmọbìnrin máa ń láàánú lójú ju ọkùnrin lọ – Olori Sekinat Elegushi
Níbo Layé Kọjú Sí: Ọmọbìnrin máa ń láàánú lójú ju ọkùnrin lọ – Olori Sekinat Elegushi
Published
Ṣe o buru ki ọkunrin gba ki iyawo aburo rẹ to jẹ obinrin maa ba awọn gbe papọ ninu ile kan naa?
Ẹwẹ, fun awọn obinrin ti gbogbo ọmọ ti wọn bi jẹ obinrin lai si ọkunrin kankan laaarin wọn, ṣe irufẹ obinrin bẹẹ le padanu ohunkohun lọjọ iwaju?
Awọn ibeere wọnyii ni a gbe yẹwo lọsẹ yii lori akanṣe eto Nibo Laye Kọju Si lori ikanni BBC Yoruba.
Bi awọn kan ṣe sọ pe ko si ohun to buru ninu ki aburo iyawo ẹni to jẹ obinrin maa gbe lọdọ ẹni, lawọn mii sọ pe ko dara rara nitori ewu to n bẹ loko longẹ ni.
Ni ti ọrọ ki gbogbo ọmọ ti eeyan bi jẹ obinrin, a ba Olori Sekina Elegushi sọrọ ti oun funra rẹ jẹ aya ọba ti gbogbo ọmọ to bi fun Kabiesi Elegushi si jẹ obinrin.
Ohun ti Olori Elegushi sọ wa ninu fidio oke yii.






