Face app: Àwọn òṣèré tíátà kan ṣàfihàn fọ́tò ọjọ́ ogbó wọn

Woli Agba
Àkọlé àwòrán, Ayọ Ajewọle asfihan bi yoo se ri tọjọ ogbo ba de
Published
Opeyemi aiyeola
Àkọlé àwòrán, Haa, arugbo soge ri ree o, Ọpẹyẹmi Aiyeọla lo ti yaa di iya agba yii
Aremu Afolayan
Àkọlé àwòrán, Hun, owe nla ni awọn aworan yii n pa fun ni pe ọjọ alẹ n bọ
Laide Bakare
Àkọlé àwòrán, Arugbo sogeri, ekisa logba ri ni aworan ọjọ ogbo Laide Bakare yii
Mosunmola Filani
Àkọlé àwòrán, Gbogbo ẹyin ewe, ẹmaa ranti pe agba n bọ wa kan wa
Mike Bamiloye
Àkọlé àwòrán, Ẹru si n yọ mi ba, ti mo ba ranti ọjọ ogbo, bawo ni iwọ yoo ti ri?
Lateef Adedimeji
Àkọlé àwòrán, Ọmọde ọjọun, o n dagba ree o, kori jẹ o pẹ laye, ko to agba da.
Sola Allyson
Àkọlé àwòrán, Ẹ o rii pe ẹrin gbajugbaja olorin Sola Allyson lekan sii lọjọ ogbo?
Odunlade Adekola
Àkọlé àwòrán, Ọdunlade ọmọ Adekọla, agba n bọ wa kan ọ o
Jide Kosoko
Àkọlé àwòrán, Agba kii pẹ kan ni