Yollywood: Ǹjẹ́ ìwọ mọ àwọn ẹbí òṣèré sinimá Yorùbá yii?

Sanyeri
Àkọlé àwòrán, Afonja Olaniyi ti wọn tun n pe ni Sanyeri, jẹ ọkan gboogi ninu awọn osere ti n panilẹrin ninu fiimu.
Published

Ẹwo àkójọpọ̀ àwòrán àwọn òṣèré Nollywood níbi tí wọ́n ti ń gbáfẹ́ pẹ̀lú ẹbí wọn.

Antar Laniyan
Àkọlé àwòrán, Ọkan gboogi ni ẹka Nollywood ni gbajugbaja oṣere ti wọn pe ni Antar Laniyan.
Lukman Raji
Àkọlé àwòrán, Oṣere ni tọkọ-taya Lukman Raji ati iyawo rẹ, Aminatu Papaapa.
Madam Saje
Àkọlé àwòrán, Oṣerebinrin Fausat Balogun ti wọn maa n pe ni Madam Sajẹ ti sisẹ ribiribi ni ẹka Yollywood.
Yinka Quadri
Àkọlé àwòrán, Ti ẹ ba n wa oṣere to n ṣiṣẹ takuntakun, Yinka Quadri ni ki ẹ kan si.
Kamilu Kompo
Àkọlé àwòrán, Adekola Tijani (Kamilu Kompo) ree pẹlu Iyawo ati ọmọ rẹ.
Jide Kosọkọ
Àkọlé àwòrán, Agba ọjẹ ninu oṣere, Jide Kosọkọ ti ni ọmọọmọ ninu isẹ tiata lorilẹede Naijiria
Àkọlé fídíò, June 12: Lekan Alabi ní kí ọmọ Naijiria rántí àwọn akọni ìjọba àwa-arawa
Akin Olaiya
Àkọlé àwòrán, Akin Olaiya re e pẹlu idile re nibi ti wọn ti n gbafẹ.

Awọn aworan yii wa lati Google ati oju opo ikansiraẹni awọn osere wọn yii,