Prince Philip: Ọkọ ọbabìnrin ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sí àtàwọn ẹbí rẹ̀ ti ṣe ẹ̀yẹ ìkẹyìn fún Duke ti Edinburgh

Posi Duke ti Edinburgh
Published

Ọbabinrin ilẹ Gẹẹsi atawọn ẹbi rẹ ti ṣe ẹyẹ ikẹyin fun ọkọ rẹ, Duke ti Edinburgh ni Windsor Castle.

Iba eeyan perete, to fi mọ awọn ẹbi atawọn ọmọ oloogbe mẹrin, eyii ti William ati Harry wa lara wọn ni wọn tẹlẹ posi ti wọn gbe oloogbe ọhun si.

Lẹyin naa ni wọn gbe posi ọhun wọ ile ijọsin St. George to wa ni Windsor Castle lori ọkọ ayọkẹlẹ land Rover.

Ni dede aago mẹta ọsan ni wọn ṣe idakẹjẹ oniṣeju kan kaakiri ilẹ Gẹẹsi.

Bo tilẹ jẹ gbagede Windsor Castle ni wọn ti ṣe eto isinkun naa, wọn ko gba ọpọ ero laye nibẹ tabi lawọn ile miran to jẹ ti ori ade ilẹ Gẹẹsi.

The Duke of Edinburgh's coffin

Mẹsan an ninu awọn mọlebi ori ade lo tẹlẹ posi Prince Philip, to fi mọ awọn ọmọọba, Anne, Charles, Edward pẹlu Andrew.

Awọn ọmọ ọbva nibii eto isinku Prince Philip, Duke tiEdinburgh ni Windsor Castle

Duke ti Cambridge ati ọmọ ọba Harry kọwọrin pẹlu ibatan wọn, Peter Philips.

Ọmọ ọba William, Duke ti Cambridge, Peter Phillips ati Prince Harry, Duke ti Sussex.

Vice Admiral Sir Timothy Laurence ati the Earl ti Snowdon na ko gbẹyin nibẹ.

Ọbabinrin Elizabeth II

Ki wọn to ṣe idakẹjẹ oni iṣẹju kan ni ọkọ ọbabinri Elizabeth de, to si lo pade Biṣọọbu agba ti Canterbury.

Posi Duke ti Edinburgh
Awọn ọmọ ogun nibi eto isinku Prince Philip, Duke ti Edinburgh ni Windsor Castle
Duchess ti Cornwall balẹ si St George's Chapel, ni Windsor Castle
Catherine, Duchess ti Cambridge
Windsor Castle
Awọn ọmọ ogun yan fanda ṣaaju eto isinku ọhun
Awọn ọmọ ogun nibi eto isinku Prince Philip, Duke ti Edinburgh ni Windsor Castle
1px transparent line
Awọn ọmọ ogun nibi eto isinku Prince Philip, Duke ti Edinburgh ni Windsor Castle
Awọn ọmọ ogun lori ẹṣin nibi eto isinku Prince Philip, Duke ti Edinburgh ni Windsor Castle

Ọpọ ero lo wo bi eto isinku naa ṣe lọ lati okeere.

Ọpọ ero lo wo bi eto isinku naa ṣe lọ lati okeere.
Ọkunrin yoo gboṣuba fun awọn ọmọ logun lori ẹṣin.

Awọn ọmọ ogun yinbọn soke bi wọn ṣe n gbe oku Prince Philip wọ inu ile ijọsin St. George.

Awọn ọmọ ogun lori ẹṣin nibi eto isinku Prince Philip, Duke ti Edinburgh ni Windsor Castle

Awọn eeyan ilu gbiyanju lati peju sibẹ ṣugbọn wọn ko gba ọpọ ero laaye nitori ilana itakete siraẹni.

Awọn ọmọ ogun lori ẹṣin nibi eto isinku Prince Philip, Duke ti Edinburgh ni Windsor Castle
Awọn abẹnikẹdun ni Windsor Castle
Eto isinku Prince Philip, Duke ti Edinburgh ni Windsor Castle
Awọn akọroyin
Ami idanimọ Duke ti Edinburgh
Ami idanimọ Duke ti Edinburgh, Prince Philip
Windsor, ilẹ Gẹẹsi.