Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ọwọ ọlọpaa ti tẹ baba onile kan to ṣokunfa bi wọn ṣe ji awọn to yale lọwọ rẹ gbe ti wọn si gbẹmi wọn
Aye o!
A gbọ pe wọn fi ipa ba ọkan lara awọn ayalegbe naa to jẹ akẹkọọ lopọ, ki wọn to gbẹmi rẹ
Hmmmmmm
Baba onilẹ ọhun ti wa lahamọ ọlọpaa bayii nibi to ti n ka boorobo
Gbọ na , nibo ni iṣẹlẹ yii ti waye?
Lọ soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
_____________________________________
Ajọ EFCC ti kede pe oun yoo pe ẹjọ kotẹmilọrun
Tako idajọ ile ẹjọ giga ilu Eko to ni gomina ipinlẹ Ekiti tẹlẹ, Ayodele Fayose ko jẹbi esun ajẹbanu ti wọn fi kan an
Ẹsun ṣiṣe owo ti iye rẹ le ni biliọnu mẹfa naira baṣubaṣu ni EFCC fi kan Fayose
______________________________________
Lorilẹede Iraq
O kere tan, ọgọta eeyan lo ti jade laye lẹyin ti ina sọ nile itaja igbalode kan niluu Kut
Oru ọjọ keje lẹyin ti wọn ṣi ile itaja igbalode ni ina ọhun ṣẹyọ
Fun ẹkunrẹrẹ