Ahmed Musa padanu ìyá rẹ̀ lẹyin aisan ranpẹ

Ahmed Musa

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ahmed Musa dabira Nàìjírìa nínú ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé lorílẹ́èdè Russia
Published
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Agbabọọlu ọmọ Naijiria Ahmed Musa ti padanu iya rẹ bayi.

O fi iroyin naa to awọn ọmọ Naijiria leti lori Twitter ni Ọjọbọ niga to ni "Ọjọ ibanuje ni ọjọ yii jẹ fun aye mi. Mo ti padanu iya mi."

Skip X post
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post

Àkọlé fídíò, Obasanjo: Atiku kìí se Áńgẹ́lì, àmọ́ yóò se dáadáa ní ìlọ́po méjì ju Buhari lọ

O ti sọ tẹlẹ pe iya oun ṣaarẹ ko to di pe o ku.

Ahmed Musa ati iya rẹ

Oríṣun àwòrán, @ahmedMusa718

Àkọlé àwòrán, iya ni wura iyebiye
Àkọlé fídíò, ìpàdé ìtagbangba ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn olùdíje sípò gomina ní ìpínlẹ̀ Eko.

Ni ana ni o fi aworan iya rẹ sori Twitter ninu eyi to fi n ki pe ki o dara le.

Iya Ahmed Musa

Oríṣun àwòrán, @Ahmedmusa718

Àkọlé àwòrán, abiyamọ ni gbogbo aye n gbadura ko duro jẹun ọmọ

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí:

Àkọlé fídíò, 2019 Elections: Èrò àwọn ọmọ Nàíjíríà se ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lóri ètó àlùfáà tàbí ìmámù lásìkò ìbò
Àkọlé fídíò, Ọ̀tọ̀ ni nkan tí wọ́n sọ fún ẹbí rẹ̀, iṣẹ́ aṣẹ́wó ni wọ́n fi n ṣe