Kí ló sọ àwọn ológbò di gbajúmọ̀ orí ayélujára ní Instabul?
Kí ló sọ àwọn ológbò di gbajúmọ̀ orí ayélujára ní Instabul?
Onírúurú nǹkan ló máa ń gbé èèyàn rin ìrìnàjà afẹ́.
Àmọ́ níṣe ni ó jẹ́ ohun ìyàlẹ́nu pé ológbò wà lára ohun tó ń gbé àwọn èèyàn ṣe ìrìnàjò afẹ́ ló sí orílẹ̀ èdè Turkey.
Níṣe ni àwọn ológbò ti di gbajúmọ̀ lórí ayélujára báyìí bí ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn tó ń rìnrìnàjò afẹ́ lọ sí Instabul ṣe ń tò láti bá àwọn ológbò yàwòrán.
Ohun tó fa èyí wà nínú fídíò òkè yìí.



