Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Gbami-gbami ko yẹ agba, ẹranko n le mi bọ wa ko yẹ ọdẹ
Lo difa fun awọn oṣiṣẹ Amẹtẹkun mẹta ti awọn agbebọn ji gbe niluu Igboho, nipinlẹ Oyo
Alepata ti ilu Igboho, Kabiyesi Ọmọwe Joel Olalere Olawuwo, ti fidi rẹ mulẹ pe wọn ri awọn ti wọn ji gbe gba pada
Ẹkunrẹrẹ wa loju opo BBC Yoruba
_____________________________________________
Awọn oniṣẹṣe ipinlẹ Ogun ti bu ẹnu atẹ lu bi wọn ṣe le awọn akẹgbẹ wọn jade nibi eto isinku Awujalẹ ilẹ Ijebu, Ọba Sikiru Kayode Adetona
Olori awọn oniṣẹṣe ipinlẹ ọhun, to tun jẹ Oluwo Iperu, Oloye Ifasola Opeodu sọ fun BBC pe ewu nla ni igbesẹ naa jẹ…
____________________________________________
Ijọba ilẹ Amẹrika ti le awọn ọdaran marun kuro nilẹ naa lọ sorilẹede Eswatini
Wọn ni orilẹede Vietnam, Jamaica, Laos, Cuba ati Yemen ni awọn ọdaran ọhun ti wa
Oniruru iwa ọdaran bii fifi ipa ba ọmọde lopọ ati ẹsun ipaniyan ni wọn fi kan wọn