Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Gbọ na, bawo ni gan ni wọn ṣe n yan Awujalẹ nilẹ Ijebu?
O n bi mi, ta ni ki n bi?
Njẹ o tun mọ pe igba akọkọ ree ti wọn yoo maa mura lati yan Awujale tuntun lati ọgọta ọdun sẹyin?
Ẹhn.. ẹhn...
Mo tilẹ gbọ pe Ifa kọ lo n yan Awujalẹ
Ṣe lootọ?
Lọ soju opo BBC lati mọ ẹkunrẹrẹ
_____________________________________________
Awọn araalu ti bu ẹnu atẹ lu ijọba orilẹede Senegal lẹyin to fofin de wiigi ati ọṣẹ ti wọn fi n bora
Olori ajọ to n ri si ọrọ aṣa, Serigne Fall Guèye ni, igbesẹ naa waye lati da aṣa orilẹede naa to ti n parẹ pada
Alaye wa loju opo wa
____________________________________________
Lorilẹede Burkina Faso
Ijọba ologun labẹ iṣakoso Ibrahim Traoré ti tu ajọ eleto idibo orilẹede naa ka
Wọn ni niṣe lajọ naa kan n fo owo ilu ṣofo lai ṣe anfani kankan faraaalu
Ileeṣẹ to n ri si ọrọ abẹle ni yoo maa ri si gbogbo ohun to jọ mọ eto idibo nibẹ lati akoko yii lọ
Fun alaye kikun