Saudi Arabia mosque: Wo àwòdamiẹnu àwòrán Mọ́ṣáláṣí Ànọ́bì ní Medina!

Published

Òpópónà Mẹ́kà mọ́ roro; àwọn èèyàn ni wọ́n n tún un ṣe to fi n rẹwà síi bi o ṣe hànde ninu awọn aworan yii.

mosalasi
Àkọlé àwòrán, Aworan Mọṣalaṣi Median laarin agbegbe to wa lalẹ, ina orisirisi lo fi kun ẹwa yii! pẹlu awọn ohun to yii ka nilu to mọ lolo yii
mo
Àkọlé àwòrán, Orule mọṣalaṣi nla ti Medina ni orilẹ-ede Saudi Arabia
Mo
Àkọlé àwòrán, Enu iboji oku Anobi Muhammed (SAW) bi wọn ṣe n ṣọọ titi di asiko yii
mo
Àkọlé àwòrán, Awọn ina alarabara ti wọn fi ṣe ọṣọ si ara awọn òpó to di mọṣalaṣi nla naa mu
mosalasi
Àkọlé àwòrán, Aworan orule apa kan ninu mọṣalaṣi naa ti awọn ile nlanla to kun fun itan ninu Kuran yii ka.
mos
Àkọlé àwòrán, Ina ti wọn kan ṣe si inu Raudah ti ẹwa rẹ kọja fifi riran lasan.
mo
Àkọlé àwòrán, Apa ibomii ni Raudah ti awọn miran ti maa n lọ gbadura bẹ Olorun
mosalasi
Àkọlé àwòrán, Nkan miran ti awọn eniyan fẹran nipa Medina ni ọna ara ti wọn fi n pe irun ninu mọṣalaṣi naa
mosalasi
Àkọlé àwòrán, Awọn alejo to wa wo iboji anobi Muhammed (SAW)
@masjid
Àkọlé àwòrán, Awọn olutọju mọṣalaṣi yii n ṣe itoju Rauda tọwọtọwọ ni Medina
mosalasi
Àkọlé àwòrán, Okan pataki ninu awọn ẹnu ọna mọṣalaṣi Medina ti wọn n pe ni abawọle ti Oba Fahd
mosalasi
Àkọlé àwòrán, Aworan mọṣalaṣi Medina lati oke pẹlu awọn ohun meremere to yii ka nilu nla