Wọnyi ni Àkójọpọ̀ àwọn àwòrán mánigbàgbé ọdún Àjínde l'Afrika.

Published

Ẹ fójú lóúnjẹ lórí àkójọpọ̀ àwọn àwòrán mánigbàgbé ọdún Àjínde l'Afrika

Aworan arakunrin kan lori agbelebu
Àkọlé àwòrán, Aworan ajọdun ajinde l'Afrika
Aworan arakunrin kan lori agbelebu
Àkọlé àwòrán, Ajọdun ajinde jẹ ọdun pataki fun awọn ẹlẹsin Kristẹni l'Afrika
Aworan arakunrin kan ati Obinrin ni South Sudan ti wọn ṣe afihan bi Jesu ṣe gbe agbelebu
Àkọlé àwòrán, Lati Naijiria titi to fi de South Sudan lawọn Kristeni n ṣe ajọdun ọdun yi
Aworan arakunrin kan to gbe agbelebu
Àkọlé àwòrán, Awọn olujọsin a ma ṣe ere to ṣe afihan iṣẹlẹ to waye lọjọ ajinde
Arakunrin to sun silẹ
Àkọlé àwòrán, Lati ọjọ ẹti rere titi di ọjọ aiku ni ajọdun yi fi n waye
Aworan arakunrin kan to gbe agbelebu
Àkọlé àwòrán, Awọn ọmọ ijọ a ma kopa ninu ajọdun naa lati fi pataki ọdun ajinde han
Aworan arakunrin kan to gbe agbelebu
Àkọlé àwòrán, Lorileede Kenya naa,awọn naa kopa ninu ajọdun ajinde