Awọn ikọ àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà ń gbáradì fún ifẹsẹwọnsẹ oni

Published

Nàìjíríà ń gbáradì fún ifẹsẹwọnsẹ pẹlu Argentina.

Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Genort Rohr ní kò sí ayé fún rìndínrìndín
Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Ọmi tàbí kí Super Eagles na Argentina ní o le yanjú ọrọ yìí
Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Ireti wa pe Musa ati Iheanacho yoo se gudugudu meje ninu ifẹsẹwọnsẹ naa
Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Oju sunukun ni Leon Balogun n fi wo ipade naa
Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Ìsinmi diẹ náà ṣé pàtàkì fún àṣeyọrí
Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Òun gbogbo tí wà ní ṣepe
Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Super Eagles ṣetan láti wò ìyá já pẹ̀lú Argentina
Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Ifẹsẹwọnsẹ yi je èyí tó lè ṣe okunfa itẹsiwaju tàbí fífi ìdí rẹmi fún ìkọ Super Eagles.
Àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Eyi ni igba ẹkarun ti Nàìjíríà yóò ma ko'ju Argentina nínú ìdíje àgbáyé.