Àkókò márùún ninu ayé Winnie Madikizela-Mandela

Published

Ìyàwó ògbóǹtarìgì olóṣèlú lorilẹede South Africa, Nelson Mandela, Winnie Mandẹla ti jalaisi lẹ́ni ọdún mọ̀kànlélọ́gọ́rin. Díẹ̀ ree lara awọn ìgbà aye rẹ̀.

Winnie Mandela
Àkọlé àwòrán, Winnie Mandela lasiko to n se ọjọ́ọ̀bí ọgọ́rin ọdún
Winnie Mandela
Àkọlé àwòrán, Àsìkò ti awọn ọlọ́pàá wa mu Winnie Mandela lori ẹsun pe o n tako ijọba apatheid
Winnie Mandela
Àkọlé àwòrán, Winnie Mandela lasiko to n kede wíwá sopin ìgbéyàwó rẹ̀ pẹ̀lú Nelson Mandela lọ́dún 1996
Winnie Mandela
Àkọlé àwòrán, Winnie Mandela n se idaro ọkọ rẹ Nelson Mandela
Winnie Mandela ati Nelson Mandela pẹlu ọmọ-ọmọ wọn
Àkọlé àwòrán, Winnie Mandela ati Nelson Mandela pẹlu ọmọ-ọmọ wọn