Ikọlu Benue: Daran daran fi ọbẹ ge baba mi lori
Published
Awọn daran daran ti gba ẹmi ọpọlọpọ eniyan lorilẹede Naijiria eyi si ti sọ ọpọ awọn ọmọ di alailobi.