Saudi Arabia, Eid /Al Fitri: Wo bí wọ́n ṣe kírun ìtúnu àwẹ̀ Ramadan 2021 ní Makkah àti Medina lónìí

Published

Lonii ni wọn kirun itunu aawẹ ni Saudi Arabia pẹlu awọn musulumi mii ni agbaye.

Saudi
Àkọlé àwòrán, Awọn Olujọsin lọ bẹẹrẹ ni Mosalasi nla ni Makkah laarọ yii
Saudi
Àkọlé àwòrán, Pẹlu ọkan kan ni wọn gbe irun duro ni Saudi ni aarọ yii
Saudi
Àkọlé àwòrán, Awọn agbaagba Aafa tó ṣaaju irun ni Makkah tẹle ofin itakete sira ẹni nitori ajakalẹ arun Covid 19
Saudi
Àkọlé àwòrán, Wọn bẹ Olorun fun alaafia agbaye ni Saudi
Saudi
Àkọlé àwòrán, Opopo Makkah mọ roro, awọn eniyan ni wọn n tun ṣe, wo ilu Makkah bo ṣe rẹwa to, ki ori je ki emi naa ko le lọ
Saudi
Àkọlé àwòrán, Awọn Aafa nlanla lo ṣaaju irun itunu awẹ Ramadan 2021 ni Makkah laarọ yii
Saudi
Àkọlé àwòrán, Wo bi awọn olujọsin ṣe n fi itara gbadura lori ohun ti wọn n fẹ loni
Saudi
Àkọlé àwòrán, Bi wọn ṣe kirun naa ni Makkah naa ni wọn ki ni Medina lonii
Saudi
Àkọlé àwòrán, Awọn tó n ṣe Umurrah lasiko yii naa ri aaye bẹbẹ adura wọn