COZA: Àdúrà kò le pa ìfipábánilòpọ̀ rẹ́, àtàwọn àkọlé mìí tó jẹyọ lórí ọrọ Fatoyinbo
Published
Awọn eniyan ko ara wọn jọ lati fẹhonu han ni ẹka ijọ COZA ni ilu Abuja ati Eko.
Àkọlé àwòrán, Ara wa kii ṣe nkan iṣere yin, a kọ ifipabanilopọÀkọlé àwòrán, Tọkunrin-tobinrin lo pejọ sibi iwọde naaÀkọlé àwòrán, Iwọde naa fa sunkẹrẹ-fakẹrẹ ọkọ loju ọna Mobolaji Bank Anthony, Ikẹja nibi ti ijọ COZA wa l'EkoÀkọlé àwòrán, Obinrin yii n sọ pẹlu akọle ọwọ rẹ pe 'ẹ maa gba awọn obinrin gbọÀkọlé àwòrán, 'Adura ko le pa ifipabanilopọ rẹ.'Àkọlé àwòrán, Ẹ ma fi orukọ Ọlọrun daabo bo afipabanilopọÀkọlé àwòrán, Sọrọ sita lasiko yii, ma pa ẹnu rẹ mọ ti wọn ba fi ipa ba ọ l'opọ.Àkọlé àwòrán, Aṣọ funfun ni awọn to fẹhonu han wọ lati polongo tako ifipabanilopọÀkọlé àwòrán, Bi wọn ṣe n sọ pe Pasitọ ko ga ju ofin lọ, ni wọn pe iwọ ko gbọdọ fi ipa banilopọ.Àkọlé àwòrán, Fọfọ̀ ni ẹnu ọna ẹka ijọ COZA to wa ni ilu Eko kun fun awọn to n ṣewọde pe ki Pasitọ̀ Fatoyinbo fi ipo rẹ silẹÀkọlé àwòrán, Ọ̀kan lara awọn akọle yii n sọ pe didaabo bo ẹni to fi ipa banilopọ kii ṣe iwa KristiÀkọlé àwòrán, Pasitọ kii ṣe Ọlọrun; Ọlọrun le dariji ọ l'ẹwọnMóríwú
Àwọn afíkun lórí ìròyìn yìí