Ọmọge Campus: Arẹwà obìnrin àti àwọn àwòrán rẹ̀

Published

Àkójọpọ̀ àwọn àwòrán olóògbé Aisha Abimbọla nígbà tó wà láyé.

Aisha Abimbọla
Àkọlé àwòrán, Ọmọ orílẹ̀èdè Canada ni Aisha
Aisha Abimbola
Àkọlé àwòrán, Aisha kẹ́kọ̀ọ́ ìmò nípa ìtọ́jú ilé ìtura
Aisha Abimbola
Àkọlé àwòrán, Aisha máa ń kópa nínú sinima olóyìnbó
Aisha Abimbola
Àkọlé àwòrán, Àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn ló pa Aisha
Aisha Abimbola
Àkọlé àwòrán, Ọmọ méjì ni Aisha fi sílẹ̀ sáyé lọ̀
Aisha Abimbola
Àkọlé àwòrán, Mùlùsùmí ni Aisha tẹ́lẹ̀, kó tó di Kristiẹni
Aisha Abimbola
Àkọlé àwòrán, Olùsọ́àgùtàn ni Aisha kò bá jẹ́, tí kò ba se òsèré tíátà
Aisha Abimbola
Àkọlé àwòrán, Aisha ti gba ọ̀pọ̀ àmì ẹ̀yẹ
AISHA ABIMBOLA
Àkọlé àwòrán, Háà! ilẹ̀ ń jẹ èèyàn